John 13:31

Jesu sọtẹ́lẹ̀ pé Peteru yóò sẹ́ òun

31 aNítorí náà nígbà tí ó jáde lọ tan, Jesu wí pé, “Nísinsin yìí ni a yin Ọmọ ènìyàn lógo, a sì yin Ọlọ́run lógo nínú rẹ̀.
Copyright information for YorBMYO